Ọgbọ́n ń pọlọ́gbọ́n
Oro buruku tohun t’erin. E je ki a maa pa ara wa lerin-in leekookan, oro naijiria ko to gbe saya lo titi. E wo eni ti ko fe ki bata olowo iyebiye re kan omi. Ase gbogbo ara lo maa kan-an.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…