Home iroyin Fashola sọ òkò ọ̀rọ̀ sí Danjuma Goje
iroyin - July 7, 2017

Fashola sọ òkò ọ̀rọ̀ sí Danjuma Goje

 

Ti awon asofin agba bar o pea won le pa Minisita fun Akanse Ise, Agbara ati Ilegbee lenu mo, o jo pe won n tan ara won je ni o.

Leyin ti okan lara awon asofin naa, Senito Danjuma Goje, laali re lori awuyewuye to n sele lori isuna owo, Fashola naa ti so oko oro si pada.

O ni Danjuma Goje ko mo bi won se n soro ti eniyan ba wa ni ile asofin.

O ni okunrin naa ni lati lo ko bi won se n se agbekale oro, ati bi eniyan se n fi opolo se eto ilu.

Fashola ni oun ko baa won asofin naa ja, sugbon oun fe fi ye won pea won ise ti oun fe se lori ona Lagos-Ibadan Expressway, oju ona Maiduguri ati Second Niger Delta Bridge.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…