Ìyàwó Tuface bú ìyáláàyá ẹni tó pè é ní ‘wor wor girl’
Iyawo Tuface faraya lojo Alamisi nigba ti eni kan pe e ni oburewa lori ero alatagba Twitter.
Jeje ni Annie Idibia gbe aworan ara re kan sori ero alatagba naa, ti awon eniyan kan si n so pe o kare.
Sugbon sa o, eni ti a wi naa wa wo obinrin yii ni iwo awomoju.
O ni kin lo n ya a lara to fi n gbe foto sita. O ni obinrin naa wowoo; iyen ‘wor wor girl.
Annie Idibia ko besu begba, o ni iya onitohun naa wowoo.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…