Làásìgbò Sickle Cell: ‘Ohun tí ọmọ Remi Surutu sọ fún un kó tó dágbére f’áyé’
Irora nla ni arun aromoleegun, iyen sickle cell, maa n fa lopo igba fun awon to ba mu.
Arun naa kii se awada rara, o je eyi to buru jojo. Bi o se n gbon obi lowo, bee lo n fa irora, ifaseyin ati idaamu ba eni to ba mu.
O jo pe iriri omo osere fiimu Remi Surutu ni eyi ki omo naa ti oruko re n je Ayo to jade laye lojo Sunday to lo.
Gege bi ohun ti okunrin kan, Ogbeni Femi Davies, so, o ni ohun ti Ayo so fun iya re nigba ti irora iku naa de ni, “Mama mi, Remi, je ki n maa lo sinmi bayii, ki iwo naa le ri ojutuu aye re.”
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…