Home iroyin Amosu fajú ro s’áwọn ẹgbẹ́ òkùnkùn
iroyin - July 5, 2017

Amosu fajú ro s’áwọn ẹgbẹ́ òkùnkùn

Gomina ipinle Ogun, Oloye Ibikunle Amosu ni ki olomo o kilo f’omo re nipa ipinle Ogun. O ni ikoko ko ni gba omi, ko tun gbeyin, ko tun wa gba soso. O ni ko si aaye bi o ti wu ki o mo ni ipinle Oun.

Amosu salaye yii ni igba ti o  se ipade pelu awon olori eso ati aabo gbogbo ni ipinle Ogun. O ni gbogbo oruko to ba wu ki awon onise ibi pe ara won, ko si aaye rara ni ipinle oun. Gomina ni oun tile gbo pe bi won se n doju le won ni ipinle Eko, won ni ipinle Ogun to mule ti Eko ni awon n bo. Amosu ni oun jeri awon ologun ipinle naa, pe won ko ni foju ire wo awon egbe okunkun to n pani, kole ti won si n ba dukia je.

O gba awon egbe-je-gbe okunkun ni imoran pe ko ba dara ki won lo ko si okun tabi osa nitori pe ko si aaye fun won ni ipinle oun, o ni ki won ma tile da ni asa rara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…