Home ÀRÒJINLẸ̀ Àjekún-ùn-yà: Àánú Dino Melaye ń semí…
ÀRÒJINLẸ̀ - July 5, 2017

Àjekún-ùn-yà: Àánú Dino Melaye ń semí…

 

Bi ere bi awada, igbese ti awon omo Ipinle Kogi kan n gbe lati yo Senito Dino Melaye kuro ni Seneeti ti di wahala si lorun bayii o.

Ajo INEC ti gba iwe ti opo eniyan buwo u, to ni ki won le Melaye kuro ni Abuja.

Ajo naa si ti so pe ile ejo nikan lo le so pe ki awon ma yo okunrin naa bi eni yo jiga.

Melaye ti lo si ile ejo pe ki INEC da igbese naa duro, to si so pe ayederu ni opo bi won se buwo lu iwe ti won fe fi yi oun lagbo da sina naa.

Nnkan naa ti n gbona fun Melaye debi pe ko tii raye aii korin ajekun-un-ya ni yoo je lasiko yii.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…