Paga! Iku mu omo osere fiimu lo
Iku alumuntu ti da ibanuje nla sile ni ile osere fiimu ti a mo si Remi Osodi Surutu.
Omodebinrin re kan to n je Ayo, lo di oloogbe, latari arun aromoleegun, iyen sickle cell, to mu u.
Isele naa da ibanuje sile laarin awon osere gan-an, ti won si n ki iya omo naa pe ki Olorun ko dawo adanu duro nile won.
Osere fiimu ti a mo si Yomi Fabiyi wa lara awon to koko gbe iroyin nla naa sita.
IROYIN OWURO naa n gbadura pe ki Olorun olojo oni ba wa tu Surutu ninu.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…