Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Messi kare lae, o gba bolu sinu awon omoge to rewa; kop e Ronaldo sibi igbeyawo re
ERÉ ÌDÁRAYÁ - July 3, 2017

Messi kare lae, o gba bolu sinu awon omoge to rewa; kop e Ronaldo sibi igbeyawo re

 

Odun boolu to sese pari yii ko dara pupo fun agbaboolu ara Lionel Messi. Idi ni pe Barcelona, iyen egbe to n gba boolu fun, ko rowo mu. Won ko gba La Liga, bee ni won ko rowo yo nibi Champions League.

Argentina paapaa, ko lee de Confederation Cup.

Sugbon Messi bori idije nla kan lopin ose to lo, nigba to gba boolu wo inu awon olomoge kan to rewa bi ododo. Omo naa n je Antonella Roccuzzo.

Opo agbaboolu nla-nla kaakiri agbaye lo wa nibi ayeye naa. Sugbon sa o, Messi ko pe olubadije re ni Real Madrid, iyen Christine Ronaldo, si ibi ayeye naa.

A ko mo idi ti ko fi pe e, sugbon awon eniyan kan so pe gbogbo awon to pe je agbaboolu fun Barcelona, yala awon to to je eni atijo tabi awon to wa nibe bayii.

Sugbon aisinibe Ronaldo ko gbodo dun un ju, tori oun naa sese bi ibeji ni.

Antonella ti bi omo meji fun Messi tele, tori won ti jo n sere ife, ojo tip e.

Adura wa nip e abimolemo ni ti eku eda o.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…