Home iroyin Kii ba ni ka yeri: Aisha pada si London lati lo se abewo si Buhari
iroyin - July 3, 2017

Kii ba ni ka yeri: Aisha pada si London lati lo se abewo si Buhari

 

Yoruba bo won ni eleru nii gbe nibi to ti wuwo; bee oro loko-laya, nnkan ki sibe. Idi niyi to fi je pe iyawo Aaare Muhammadu Buhari, iyen Iyaafin Aisha Buhari, ti se irinajo pada si London, ni orile-ede United Kingdom, nibi ti Buahri ti n gba iwosan.

Ni nnkan bii osu kan seyin ni Aisha koko ti lo wo oko re nibe.

Nigba to de, iroyin ayo lo mu wa pe Olorun ti n gbakoso lori idagunle ti Buhari ni.

Sugbon sa o, oniroyin Sahara Reporters so pe awon alagbara kan ko je ki obinrin naa ri baale re. Iyaafin Buhari ko fesi le eleyii; yala o je otito ni o, tabi o fe ki won maa gbe enu won ni igbekugbee.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…