Home Orisirisi Olùgbé VGC Lekki, Eko rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ìjọba
Orisirisi - July 2, 2017

Olùgbé VGC Lekki, Eko rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ìjọba

Awon olugbe Victoria Garden City ni Lekki to wa ni ipinle Eko ma ti ke gbajare si ijoba ipinle Eko, won ni ki won ma se je ki omi o gbe awon lo. Won ni “omi yale agbara ya soobu” yii n po. Won ni ki ojo maa tii kan ni, ko si eni to le gbe moto ayokele koja mo afi awon to ba ni Jiibu to ga nile daadaa.

Awon olugbe ibe to ni ona abayo tile ti n kuro ni adugbo naa. Won ni wahala naa ti n po ju, nitori bi omi yii se n ba oko je lo dena awon omo lati lo ileewe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…