Home iroyin Ko pon dandan ki Buhari so iru aisan to n se e fun omo  Naijiria – Afe Babalola
iroyin - July 2, 2017

Ko pon dandan ki Buhari so iru aisan to n se e fun omo  Naijiria – Afe Babalola

 

Opomulero omo Yoruba kan, Oloye Afe Babalola, ti so pe kii se dandan ni pe ki Aare Muhammadu Buhari so hulehule ailera re fun awon omo Naijiria.

Oloye Babalola, to je ogbontarigi agbejoro, to tun je oludasile Afe Babalola University to wa ni Ipinle Ekiti, se alaye pe oro ailera Aare je eyi to je ti ara re, eyi ti awon oloyinbo n pe ni personal matter, ti kii se ti gbogbo ilu, public matter.

Agbejoro naa so pe ofin ko pon on ni dandan fun Buhari lati maa ka boroboro lori oro naa.

Sugbon sa o, Oloye Babalola fi ara mo ipe ti opo eniyan n pe lori atunto orile-ede yii, ti a mo si restructuring.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…