Fídíò ibi tí àwọn ará ìlú ti fìbínú já òsìsẹ́ iná mọ̀nà-mọ́ná síhòhò látorí òpó
Gbogbo osise oba, oko oba,ada oba ko ni sa wa lese. Ti won ba ran wa nise eru, e je ki a maa fi ti omo jee. Ara n kan awon ara ilu bayii. Yoruba bo, won ni “ki ile to posika, ohun rere a ti baje”. Osise ti awon ara adugbo yii fiya je, ti Eledua ba je ki o yee, bi o tile lo ile ejo, ohun to baje ti baje. Yoruba ni ” o nan mi ko dun mi, a ko le fi we eni ti won ko na rara”. E je ki a fi fidio yi se arikogbon ….
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…