Home Orisirisi Okorocha gbéná wojú Fayose
Orisirisi - June 29, 2017

Okorocha gbéná wojú Fayose

Gomina ipinle Imo, Ogbeni Rochas Okorocha ni oro ti Ogbeni Ayodele Fayose tii se gomina ipinle Ekiti so ni ana ko dara rara. Ana ni Foyose ni ki Buhari roju kowe fi ipo Aare sile ki ilu le toro . O tun salaye pe eyi maa le je ki o foju to aisan to n see.

Okorocha ni iru oro bee ko ye ko maa jade lenu agbalagba to fe ki ilu toro. O ni pelu aibale okan to wa nilu yii, ko tun ye ki a ri agbalagba to tun maa runa si isoro ilu yii. Rochas wa tun ni ko le ya ohun lenu pupo fun Fayose nitori pe bi o se maa n soro ni tire niyen bi o tile je pe ko dara. O ni aisan o ki n se ohun ti enikeni ni ikapa lori re nipa idi eyi, ko ye ki enikeni maa fenu saata eni to ba re paapaa julo olori ilu ye ni eni aponle.

Okorocha gba awon ara ilu nimoran pe ki won ma se di nnkankan mu ninu ohun ti Fayose ba so nipa Buhari nitori pe “ota eni kii pa odu oya” ni oro Foyose ati Buhari lati odun 2015.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…