Home LÁGBO ÀRÍYÁ Mercy Aigbe àti baálé rẹ̀ tẹ́lẹ̀ sì ń fi ara wọn se ẹlẹ́yà
LÁGBO ÀRÍYÁ - June 29, 2017

Mercy Aigbe àti baálé rẹ̀ tẹ́lẹ̀ sì ń fi ara wọn se ẹlẹ́yà

 

Kii se iroyin tuntun mo rara pe osere fiimu Mercy Aigbe ati baale re tele, iyen Ogbeni Lanre Gentry.

Ohun ti o kan wa toju su eniyan ni bi awon mejeeji tun se n fi ara won se eleya.

Won ko si lodo ara won mo, leyin ti Mercy binu ko jade, lori esun pe Lanre n lu oun ni alupa-mokuu.

Koda, okunrin naa sun atimole fun bii ojo meloo kan, ti won si ti gbe ejo re lo si ile ejo.

Sibesibe, ojoojumo ni won n pa owe mo ara won.

Eyi to tun n lo nigboro bayii ni bi Mercy se dogbon gbe gbolohun kan ti Lanre fi ranse si i nigba ti nnkan ko tii daru tan.

Ninu oro naa ti won jo so lori ero alatagba, Lanre n be iyawo re pe ko ma binu mo, ati pe oun ko nii doju ogun abele ko o mo – iyen domestic violence.

Idi ti Mercy se te oro naa jade nip e o fe ki awon eniyan mo pe iro ni Lanre n pa nigba to ni oun ko lu oun (Mercy) bi eni lu baara ri.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…