Mo ti ni ololufe miran – Doris Simeon
Osere fiimu pataki ti a mo si Doris Siemon ti so pe oun ti ni okunrin miran to n ku fun oun o.
Doris Simeon ko tii so oruko eni naa, bee ko tii gbe aworan re han si araye.
Doris ti se igbeyawo tele pelu Daniel Ademinokan, sugbon igbeyawo naa daru, to si je pe osere fiimu miran, Stella Damasus, ni Daniel n ba se loko-laya bayii.
Ninu iforowanilenuwo kan to sese se, Doris ni oun ni alaafia pelu ololufe oun naa, sugbon awon ko tii soro lo sibi sise igbeyawo.
O se alaye pe lopo igba, mareeji kii se ife (love). O ni opo igbeyawo to wa laarin awon onifiimu, arenji ati oju aye lasan ni.
O ni oun sese pari ise lori fiimu merin kan ni, ti meji wa ni ede oyinbo, ati meji ni Yoruba.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…