Home Orisirisi Buhari ní láti fi ipò Ààrẹ sílẹ̀ – Fayose
Orisirisi - June 28, 2017

Buhari ní láti fi ipò Ààrẹ sílẹ̀ – Fayose

Gomina ipinle Ekiti, Ayodele Fayose ni o n ba awon oniroyin soro ni aaro oni pe, Aare Buhari ti lo ojo metalelaadota (53days) ni ilu Oba pelu aisan re. O ni ko si iroyin gidi kankan lati odo re tabi lati ile ise Aare nipa Buhari. O ni loooto ni a gbo ikini ede Hausa kan fun awon omo Naijiria.

Fayose ni eleyii ko to gbekele, nitori pe aisan naa ti n di ” aisan to n se ogoji, lo n se oodunrun, ohun to n se aboyade, gbogbo oloya lo n se”. O ni, eyi ko dara to fun orileede to ba fe ni ilosiwaju. O ni, o ti wa to asiko bayii fun Aare Buhari lati fiwe fipo sile ki itesiwaju le ba ilu yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…