Home iroyin Baba Adeboye fe da seria fun awon obayeje pasito Ridiimu
iroyin - June 28, 2017

Baba Adeboye fe da seria fun awon obayeje pasito Ridiimu

 

Adari Agba kaakiri agbaye fun ijo The Redeemed Christian Church of God, Pasito E. A. Adeboye, ti setan ati fi oju awon pasito soosi naa ti won n huwa ibaje han eemo.

Kaakiri agbaye, esun n waye pe awon kan lara awon pasito naa n se modaru owo, won si n se gabagebe pelu omo ijo ati Olorun to ye ki won maa sin.

Sugbon Alagba Adeboye ni oun ko nii fi epo bo iyo lori enikeni ti aje iru esun bee ba si mo lori.

O wa ro gbogbo eniyan to ba mo enikeni to n huwa ibaje pe ki o bun oun gbo.

O ni ki won ranse si oun nipa kiko nipa isele bee, ki won si fi ranse si adiresi alatagba oun, iyen emal: contact@eaadeboye.com.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…