Home iroyin Aramanda! Ogbologbo ajinigbe Evans gbe oga olopa lo si ile ejo
iroyin - June 28, 2017

Aramanda! Ogbologbo ajinigbe Evans gbe oga olopa lo si ile ejo

 

 

Oore ti wa fe di odi bayii o, esuro padi da, o n le aja!

Gege bee ni ti ogbologbo ajinigbe ti oruko re n je Chukwudumeme Onwuamadike, ti opo eniyan mo si Evans.

O se bebe ni ojo Alaaruba ana nigba to gbe Oga Olopaa Agba ni Orile-ede yii, Inspector General Ibrahim Idris, ati awon ajo miiran lo si ile ejo.

Awon to tun gbe lo si ile ejo ni ile ise olopaa gan-an, iyen Nigeria Police Force, Komisanna olopaa ni Ipinle Eko ati ajo Special Anti-Robbery Squad, Lagos State Police Command.

Pelu iranlowo loya re, Ogbeni Olukoya Ogungbeje, Evans ni ki ile ejo pase ki won fi oun sile, bi bee ko, ki awon olopaa gbe oun lo si ile ejo kiakia.

O jo pe bi o se wa ni atimo tu su u.

O si so pe labe ofin Naijiria, awon olopaa ko lase lati gbe eni ti won ba fesun kan sodo lai gbe e lo si ile ejo.

Ojo kewaa osu yii ni Evans ti

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…