Home iroyin Òyìnbó Amerika sọ ìdí tó fi fún àbúrò rẹ̀ lóyún
iroyin - June 26, 2017

Òyìnbó Amerika sọ ìdí tó fi fún àbúrò rẹ̀ lóyún

 

Oro awon oyinbo, Olorun lo ye. Gege bee ni ti arakunrin oyinbo kan to fi ilu Los Angeles, ni Amerika, se ibujokoo.

Okunrin naa ti oruko re n je Gavin lo fe aburo re, to si fun un loyun.

O wa so idi re ti oun fi se bee. O ni ife ti oun ni si omobinrin naa po gidi.

Gavin so pe ife ko see fi owo bo mole. O ni ti eniyan ba nifee eni kan, kii se ohun to se e fi pamo tabi fi owo bo mole rara.

Gavin ati aburo re to fun loyun ni won wa ninu foto yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…