Ìjọba àpapọ̀ lé àwọn asẹ́wó kúrò ní Abuja
Wahala ti de ba awon okunrin to feran lati maa ba asewo lopo ni ilu Abuja bayii o, tori ijoba apapo ti le won kuro nibe.
O ni awon ti arun opolo n se ati awon omo kata naa wa lara awon ti won le lo si ibi ti won ti wa.
Awon asewo wa lara awon eniyan bii egberin ti awon to n sakoso olu ilu Naijiria naa, iyen Federal Capital Territory, le lo si ilu won.
Minisita fun FCT, Alhaji Muhammed Musa Bello, lo so eyi di mimo.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…