Ìdí tí mo fi fún àbúrò mi lóyún – Òyìnbó sọ̀rọ̀
Oro awon oyinbo, Olorun lo ye. Gege bee ni ti arakunrin oyinbo kan to fi ilu Los Angeles, ni Amerika, se ibujokoo.
Okunrin naa ti oruko re n je Gavin lo fe aburo re, to si fun un loyun.
O wa so idi re ti oun fi se bee. O ni ife ti oun ni si omobinrin naa po gidi.
Gavin so pe ife ko see fi owo bo mole. O ni ti eniyan ba nifee eni kan, kii se ohun to se e fi pamo tabi fi owo bo mole rara.
Gavin ati aburo re to fun loyun ni won wa ninu foto yii.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…