Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Owó lobìnrin mọ̀, Ighalo ní olólùfẹ́ òun àkọ́kọ́ sálọ nígbà tí kò tíì s’ówó lọ́wọ́ òun
ERÉ ÌDÁRAYÁ - June 19, 2017

Owó lobìnrin mọ̀, Ighalo ní olólùfẹ́ òun àkọ́kọ́ sálọ nígbà tí kò tíì s’ówó lọ́wọ́ òun

 

Ti agbaboolu fun Super Eagles, to tun n gba boolu fun Watford ni orile-ede England tele, Odion Ighalo, ba raaye ni, orin ti ki ba maa ko ni orin Ebenezer Obey kan, nibi to ti so pe ‘Olomobinrin yi ko moore/ Olomobinrin yii ko moore…/Owo ko ni gbogbo nnkan/ Olomobinrin yii ko moore.’

Idi ni pe agbaboolu naa ti se iranti bi omobinrin kan ti won jo ni asepo tele se sa danu tori pe oun ko rowo yo lapo.

Ighalo ti di olowo tabua bayii, to si je pe owo nla lo n gba ni orile-ede China, nibi to ti n gba boolu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…