Home LÁGBO ÀRÍYÁ Irọ́ ni wọ́n pa mọ́ mi, n kò ta fídíò òkú Moji Ọlaiya – Gbenga Adewusi
LÁGBO ÀRÍYÁ - June 18, 2017

Irọ́ ni wọ́n pa mọ́ mi, n kò ta fídíò òkú Moji Ọlaiya – Gbenga Adewusi

 

Fidio kan ti won se lori isinku Moji Olaiya ti fe ko agba onifiimu ti a mo si Gbenga Adewusi siyonu o.

Won se akojopo ibanidaro ati isinku arabinrin naa sinu fidio naa ti won pe akole re ni CANADA TO GRAVE: Moji Olaiya.

Lona kinni, awon amoye so pe akole ti won fun fidio naa ko dara. Won gba pe ede alailaanu ni. Bakan naa, won ni nnkan buruku ni bi won se fe maa ta fiimu naa, tori o da bi eni pe won fe maa fi oku Moji pawo ni.

Idi niyi ti opo eniyan fi n soro abuku si Gbenga Adewusi, eni to ni Bayowa Films.

Sugbon sa o, oun naa ti salaye pe fidio naa kii se fun tita. O ni won se e lati seye fun oloogbe naa ni.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…