Home LÁGBO ÀRÍYÁ Alhaja lọ́la: Dayọ̀ Amusa wà ní Umura
LÁGBO ÀRÍYÁ - June 18, 2017

Alhaja lọ́la: Dayọ̀ Amusa wà ní Umura

 

Bi awon ololufe osere fiimu ti a mo si Dayo Amusa ko ba ri i nita lenu ojo bii meloo kan, ki won ma jaya rara o. Idi ni pe Umura ni osere naa wa lowo-lowo yii.

Otito oro naa je jade nigba ti o ju foto re sode lose to lo, nibi ti o ti n seto Umura ni Mecca, ti oun naa wo aso esin, to si weri bii Alhaja lola.

O seese ki Dayo o se fiimu to jemo iriri re nigba to ba ti Mecca de, tori awon onitiata feran lati maa mu iriri won lo.

Ti a ko ba gbagbe, Fathia Balogun naa se irinajo si Mecca laipe yii.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…