Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ààwẹ̀ kò ní kí ènìyàn má seré ìdárayá – Funkẹ Adesiyan
LÁGBO ÀRÍYÁ - June 18, 2017

Ààwẹ̀ kò ní kí ènìyàn má seré ìdárayá – Funkẹ Adesiyan

 

Osere fiimu ti a mo si Funke Adesiyan ti pe akiyesi awon Musulumi ati awon miiran ti won gba aawe si bi o se ye ki eniyan maa daraya lasiko aawe.

O fe ki awon eniyan mo pe ko ye ki eniyan maa ka guoguo, tabi ko maa kanra gogo nitori pe o n sise laada.

Funke fi apere yii han nigba to lo se ere idaraya ti awon oloyinbo n pe ni physical exercise, iyen ninu ile ere idaraya ti a mo si gymnasium.

O ni anfaani to wa ninu ki eniyan maa se iru idaraya bee po, tori o wulo fun ilera.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…