Home Orisirisi Èèmọ̀ n’ìlú Àkúrẹ́: Ìyàwó pásítọ̀ pokùnso
Orisirisi - June 13, 2017

Èèmọ̀ n’ìlú Àkúrẹ́: Ìyàwó pásítọ̀ pokùnso

Kayefi nla kan ti sele ni ilu Akure, nigba ti Iyaafin Opeyemi Babatola, eni to je iyawo pasito, pa ara re.

Yara kan ninu ile won ni obinrin naa ti pokunso, ti haa-hin-in si n se baale re, iyen Pasito Adeolu Babatola.

Iroyin fi ye wa pe obinrin naa so fun baale re pe oun n lo fun adura pataki kan ni, ti awon ebi re ko si mo pe inu yara kan lo yo boro si.

Ibe naa lo ti pokunso.

A gbo pe okunrin naa wa pelu awon olopaa bayii, nibi ti won ti n wa ojutuu si kayefi naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…