Home Orisirisi Orji Kalu fẹ́ kí Gani Adams di Ààrẹ Ọ̀nà Kakaǹfò
Orisirisi - June 12, 2017

Orji Kalu fẹ́ kí Gani Adams di Ààrẹ Ọ̀nà Kakaǹfò

 

Gomina Ipinle Abia tele, Dokita Orji Kalu, ti so pe nnkan to dara ni bi Adari Agba fun egbe OPC, Otunba Gani Adams, ba di Aare Ona Kakanfo tuntun.

Kalu so oro yii ni ojo Monday nigba ti won n se eto kan lori iranti ibo June 12, nibi ti Oloye MKO Abiola ti bori sugbon ti awon ijoba Babangida at Abacha ko je ko de ipo.

Eto naa waye ni Excellence Hotel, ni Ogba, ni Ipinle Eko.

Nigba to n soro nibe, Kalu ni Gani Adams ni gbogbo ohun to ye ki Aare Ona Kakanfo ni.

Koda, o ni ohun ati awon kan ti n ba Alaafin ti Oyo, Oba Lamidi Adeyemi, soro, lori pe ki Iku Baba Yeye fun Gani ni oye naa.

Abiola lo je oye naa gbeyin, ti ipo naa si ti sofo lati odun 1998 ti o ti di oloogbe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…