Home iroyin Ọwọ́ tẹ olè tó fẹ́ gbé kọ̀m̀pútà ní Shoprite
iroyin - June 10, 2017

Ọwọ́ tẹ olè tó fẹ́ gbé kọ̀m̀pútà ní Shoprite

 

Owo palaba arakunrin kan segi ni gbajugbaja oja Shoprite to wa ni Alausa, Ikeja, lose to lo, nigba to fe ji komputa alagbeka, iyen laoptop, gbe.

Inu moto kan ti won paaki sile ni okunrin naa ti fe gbe e.

A gbo pe eni to ni moto ti wo inu Shoprite lo, ti ko mo pe karanbanikan n so oun lowo so oun lese.

Okunrin naa ni kokoro moto orisiirisii lowo, okan lara re lo si fi si moto naa.

Sugbon awon alaabo oja naa ri  lookan, ti won sig baa mu sinkin.

A gbo pe iru isele bee ti maa n sele. Eyi lo fa a ti awon sikioriti fi la oju won mejeeji sile.

Ohun ti o ya opo eniyan lenu ni pe okunrin naa wo aso bii alakowe, ti oju re n dan gbere.

Won ti fa a fun awon olopaa bayii.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…