Home Orisirisi Dino Melaye,máa padà bọ̀ wálé – kogi west
Orisirisi - June 5, 2017

Dino Melaye,máa padà bọ̀ wálé – kogi west

Awon ara ipinle kogi to dibo yan Seneto Dino Melaye si Abuja ni eyi to doju ti awon to, ki o maa pada bo.

Won ni ekuro ni awon ni ko lo ra,  bawo ni omo eran se wa n wo igba re? Oni ejo, ola aroye ni lati odun meji to ti de ibe. Won ni awon oro alufansa, orin ote, orin owe ati awon iwa igberaga ko ni awon ran an lati lo se.

Lara iwe enini ti awon ara kogi ko ni won ti salaye pe, lati odun meji to ti n soju awon, ko si idagbasoke kankan lati odo re. Afi awon oko boginni lorisiirisii pelu akole Dino 1, Dino 2, Dino 3 ati bee bee lo nikan ni awon n ri, to iya si n je opo awon to dibo yan an.

Dino Melaye da won lohun kia pe ere omode ni won n se, won ko le yo oun bi eni yo jiga bee.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…