Soyinka so ede Yoruba nita gbangba
Enu ya opo eniyan ni ilu Abeokuta lose to lo nigba ti gbankogbi onkowe, Ojogbon Wole Soyinka, so Yoruba to dan moranin-moranin.
Eyi waye lasiko ti won n se odun ile – Drum Festival.
Nigba ti Soyinka gun itage lati so oro, opo eniyan ro pee de Oyinbo igilango to maa n so ni yoo so.
Sugbon nigba to ki Yoruba mole, enu ya won debi wi pe won n pa atewo leralera ni.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…