Oritsefemi segbeyawo leyin ti obinrin meta bimo fun un
Akorin igbalode ti a mo si Oritsefemi ti kuro ni egbe apon bayii.
O ti fi awon akegbe re bii D’Banj ati Banky W. sile si egbe apon.
Oritsefemi se igbeyawo pelu obinrin orekelewa kan ti oruko re n je Nabia Flash.
Sugbon sa o, ki akorin naa to se eyi, ile ti we.
Idi ni pe obinrin meta ti ko few ole ni won ti bimo fun un tele.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…