Olamide ko fe lo si orun apaadi
Ohun to wu ni nii po loro eni, ologun eru ku, aso re ko si ju meta.
Bee, ohun ti onikaluku n ro lokan lasiko kan ko jo ara won.
Gege bee ni ti akorin hip hop ti a mo si Olamide.
Arakunrin naa ti awon ololufe re n pe ni Bado, latari awon orin soki-soki to maa n ko, so pe loooto, o dara ki eniyan lowo, ko si lokiki. Sugbon iye kii se opin aye.
Olamide so lopin ose to lo pe ohun to wu oun ju nip e ki oun lo si ile ogo nigba ti oun ba kuro ni aye yii.
Eyi tumo si pe ko fe pari gbogbo nnka si orun apaadi.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…