Home ÀKỌ̀TUN Ninu awo orin tuntun, Obesere ni alaimore ni Wasiu
ÀKỌ̀TUN - òpómúléró - Orisirisi - April 26, 2017

Ninu awo orin tuntun, Obesere ni alaimore ni Wasiu

Awo orin tuntun kan ti Abas Akande Obesere sese se yoo tubo da kun auyewuye to n lo lowo lagbo orin fuji o.

Ko si aniani pe oro ti Wasiu so lori idasile fuji, to ni Barrister ko lo da orin naa sile ni Obesere fe fi orin fesi le.

O pe akole orin naa ni INGRATE, ti o tumo si alaimoore.

Awon alase egbe onifuji, iyen FUNMAN, ti n pete bi ija naa yoo se role, sugbon pelu orin ti Obesere tun n gbe sita yii, Olorun lo mo ibi oro n lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…