Home Èfè ati Àwàdà Leyin odun kan aabo, iyawo Odunlade Adekola bi omo miiran

Leyin odun kan aabo, iyawo Odunlade Adekola bi omo miiran

Mewaa n sele ninu idile osere fiimu pataki, Odunlade Adekola.
Sugbon isele ayo gbaa ni.
Ni nnkan bii odun kan aabo ni iyawo re, Iyaafin Ruth Adekola, bi omokunrin lanti-lanti kan.
Iyen je omo elekerin won.
Sugbon awon tokotaya naa ti fihan pe kinni ohun si wa lara awon gidigidi o.
Idi nip e lose to lo, obinrin naa tun bi omo miiran.
Ni odun 2003 ni won se igbeyawo.
Odunlade ni oun dupe lowo Oluwa lori ohun to n sele ninu ile oun.
O ni loooto, oun ati iyawo oun maa n ni gbonmisii-omi-o-to-o lawon asiko kan, sugbon didun didun ni ti ireke.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…