Home LÁGBO ÀRÍYÁ Iyawo Wasiu Ayinde bi omobinrin lanti-lanti

Iyawo Wasiu Ayinde bi omobinrin lanti-lanti

Osu to lo ni akorin fuji pataki, Wasiu Ayinde K1 de Ultimate, pe eni ogota odun.

Sugbon sa o, o jo pe akorin naa sese bere aii gbe nnkan rere se ni.

Idi ni pe iyawo re, Iyaafin Titi, sese bi omo tuntun lanti-lanti ni.

Pelu idunnu ati ayo ni awon ololufe akorin naa se n ki won ku oriire, ti won si n so pe Olorun a woo mo naa.

Wasiu ni ope nla ni o ye fun Olorun, Oba to je ki omo naa waye pelu itura.

O wa so ninu atejade kan pe omo naa ni won so ni Omooba Fawzeeyah Melissa Adebosipo Olasunkanmi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…