Home Orisirisi Iku seru ba wa, o mu ISIAKA ADELEKE lo.
Orisirisi - April 23, 2017

Iku seru ba wa, o mu ISIAKA ADELEKE lo.

Ko si n ti yoo seru ba koowa ju aare lo.lku gan an ki i seru baayan. Tori n ti eru le ba lara eda yoo ti pada si odo olowo o re.

O w a di ko ..ko… ko.. bi omi tu lo lorun akerengbe.Ile giri giri reyin eni ti n te e.Kira kita eda pin sile oniha kan.Taya tomo,tore tebi rele, okuwa eeyan toti deni akolebo bi eebu isu. I ba se pai ku laye,ara igba un da?

Orun dede ma kanju ,gbogbo wa la n bo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…