Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Wahala ti mo n se lori ere Jenifa kii se keremi – Funke Akindele
ERÉ ÌDÁRAYÁ - iroyin - March 25, 2017

Wahala ti mo n se lori ere Jenifa kii se keremi – Funke Akindele

Eni ti yoo ga, ese re yoo tin-in-rin.
Bee, kii se ere omode lati sise goke agba.
Eni ti a n pasamo mo ni Funke Akindele, eni ti irawo re tubo n yo sii.
Ere re ti a mo si Jenifa lo wa n so o di gbajugbaja sii.
Bi o se n ni owo sii, lo n kole nla, to si n gba ami eye lori ise naa.
Sugbon sa o, Funke ti so pe wahala ti oun n se lori Jenifa kii se keremi.
Ni bi oun ji, bi oun sun, bi oun n jeun, oro ere Jenifa naa ni oun n ro.
O wa so pe oko oun, Abdurasheed Bello, wa leyin oun bi ike, to si je pe oun ni igi to wa leyin ogba ti ko je ko wo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…