Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Mourinho f’abuku kan awon to n bu Pogba
ERÉ ÌDÁRAYÁ - iroyin - March 25, 2017

Mourinho f’abuku kan awon to n bu Pogba

Adari egbe agbaboolu Manchester United, Jose Mourinho, ti so pe ki awon ti won n wenu si Pogba lara o gbenu won sohun-un.
Opo eniyan lo n so pe owo iyebiye ti Mounrinho fi ra agbaboolu naa, bi owo anadanu ni.
Opo bilionu naira (89 million dollars) ni won fi ra Pogba, ti awon ololufe boolu si ro pe oun ni yoo gba liigi fun Man U.
Sugbon latigba ti idije EPL ti bere ni saa yii, foniku-foladide ni Pogba n se.
Eyi lo mu ki won maa fenu saata re pe oku aparo ni Mourinho ra.
Sugbon Mourinho naa ti soro.
O ni oun mo ohun ti oun ko owo le lori.
O ni Pogba mo ohun to n se, to si je pe oun mo ipa to n ko lori papa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…