Home LÁGBO ÀRÍYÁ Gbogbo igba ni oko mi maa n je ki ori mi o tanna sile – Omotola
LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - March 25, 2017

Gbogbo igba ni oko mi maa n je ki ori mi o tanna sile – Omotola

Okan lara awon osere fiimu ti Olorun fi igbeyawo ke, Omotola Jalade-Ekeinde, ti so lara asiri bi nnkan se n dan moran laarin oun ati baale re o.
Gege bi osere ti won tun maa n pe ni Omo Sexy se so, o ni gbogbo igba lo maa n je ki ori oun o gbona janjan, ti o si maa n je ko oun yofee.
O so oro yi lati orile-ede Morocco, nibi ti oun ati oko re sere lo.
Opo igbeyawo laarin awon osere lo maa n daru.
Sugbon, gege bii igbeyawo Olu Jacobs ati Joke Silva, moranin-morain ni aarin Omotola ati oko re to je awako baalu dun

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…