Home òpómúléró Ija ilara be sile laarin Ambode ati Fashola

Ija ilara be sile laarin Ambode ati Fashola

Yoruba bo won ni anjuwon ko see wi lejo, ija ilara ko tan boro.
O jo pe ija oselu to be sile lasiko idibo odun 2015, nigba ti Ogbeni Babatunde Fashola ko koko fe ki Gomina Akinwunmi Ambode di asoju egbe APC, ko tii tan nile o.
Alagba Sasore ni Fashola gbe ponyin nigba naa, nigba ti Asiwaju Bola Tinubu fa Ambode kale.
Leyin-o-reyin, Ambode ni kinni naa ja mo lowo, ti Fashola si pada sodo oga re, iyen Tinubu.
Sugbon lati igba ti Ambode ti de ipo, ti Fashola naa si di minisita, ko jo pe aarin won dan moran to bee.
Oro naa jeyo lojo Alaruba, nigba ti Ambode ke gbajare pe ile ise ijoba ti Fashola n se ololri le, iyen Ministry of Works, n se adina-gbooku fun ijoba Eko.
O ni oju ona papako ofurufu ti Murtala Muhammed International Airport, to ri gbongun-gbongun, ti ijoba oun fe se, Fashola ko fun oun laye rara.
Sugbon sa o, ile ise Fashola naa ti soro pada.
O ni iro ni, oun ko di Ambode lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…