Home iroyin Dayo Amusa ni se dandan ni k’obinrin o l’ade ori ni?
iroyin - LÁGBO ÀRÍYÁ - March 14, 2017

Dayo Amusa ni se dandan ni k’obinrin o l’ade ori ni?

Osere fiimu ti a mo si Dayo Amusa ti ju ibeere nla kan lule lori ero alatagba intaneeti, nigba to beere pe se dandan ni ki obinrin o lo sike oko ni.
Gege bi o ti wi, o ni se ese ni ki obinrin o ma ni okunrin kankan gege bi oko.
O ro awon eniyan to ba fed a si oro naa pe ki won ma ro ti oun ti oun ko tii lo sile oko kankan o.
Dipo bee, o ni ki won ro oro naa taara.
Bayii ni awon eniyan bere sii so orisiirisii oro.
Awon kan ni ko si ohun to dara bii ki obinrin loko, ti awon kan ni kii se oran.
Bakan naa, awon kan n ki Dayo Amusa wa woroko fi sada, k obo soode okunrin kan

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…