Wàhálà ńlá dé bá àwọn ọmọ Naijiria tó fẹ́ lọ sí Amẹ́ríkà
Idaamu nla ti de ba opo omo Naijiria ti won fe se irin ajo lo si orile-ede Amerika bayii o.
Bi o tile je pe won ni iwe irinna ti a mo si visa, awon alase Amerika kan n da opo won pada ni.
Olubadamoran fun Aare Muhammadu Buhari lori oro awon omo Naijiria to wa ni ile okeere, Iyafin Abike Dabiri-Erewa, lo so eyi lojo Monday.
O wa ro awon eniyan ti won ba n gbero lati lo si orile ede naa ko ni suuru fungab die na, to ba je pe ohun ti won n lo se ko bap on dandan.
A gbo pe ilana gbele-e ti olori Amerika tuntun, Ogbeni Donald Trump, sese gbe kale lo fa rotiroti naa.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…