Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Yègèdè, National Stadium bọ́ sọ́wọ́ ìjọba Èkó Àḿbọ̀dé gbá Table Tennis
ERÉ ÌDÁRAYÁ - Orisirisi - March 5, 2017

Yègèdè, National Stadium bọ́ sọ́wọ́ ìjọba Èkó Àḿbọ̀dé gbá Table Tennis

Gomina Ipinle Eko, Ogbeni Akinwunmi Ambode, se afihan bi oun se mo tabu tenissi gba si lose to lo, nigba ti oun ati ilumomika agba-teniisi, Funke Osonaike, jo waa ko.
Bi o  tile je pe Funke dewo fun Ambode, gomina naa fihan pe oun mo owo yi, ti awon eniyan sis a a ni atewo.
Idije naa waye lasiko ti Minisita fun Ere Idaraya, Alagba Solomon Dalung, pelu Gomina lo si papa isere National Stadium, nibi ti won ti fa gbagede naa le ijoba Eko lowo.
Ijoba Ambode ni yoo tun un se bayii, ti yoo si di amulo fun awon eniyan.
Bi a ko ba gbagbe, ijoba Ambode ti pinnu ati tun gbagede osere National Theatre naa se

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…