Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ṣọlá Sóbọ̀wálé sọrọ lórí àwọn tí wọn lọ sẹ̀wọ̀n nílùú òyìnbó
LÁGBO ÀRÍYÁ - March 5, 2017

Ṣọlá Sóbọ̀wálé sọrọ lórí àwọn tí wọn lọ sẹ̀wọ̀n nílùú òyìnbó

Gbajugbaja onifiimu, Sola Sobowale, ti so pe enu awon to n so isokuso nipa oun yoo wo wowo laipe yii.
Ni nnkan bii odun meloo seyin ni Sobowale ko lo si oke okun.
Nigba to wa ni ilu oyinbo, awon kan ni eru oyinbo lo loo se, depi pe o n ba won fo oku.
Awon kan tunn ni o tile kan ijangbon debi pe won ju u si ewon.
Sugbon osere naa ti irawo yee tubo n yo lojoojumo so pe gbogbo awon to n so isokuso naa yoo tie nu bole laipe yii nigba ti ohun ba so hulehule oro.
Sobowale kopa pataki ninu fiimu tutun kan to n ta warawara ni sinimo, iyen THE WEDDING PARTY.
O ni oun dupe lowo Olorun pe gbogbo fiimu ti oun ba se nibe lo n yori sir ere.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…