Home iroyin K1 dáná oúnjẹ fún Steve Ayọ̀rìndé …
iroyin - Orisirisi - Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - March 5, 2017

K1 dáná oúnjẹ fún Steve Ayọ̀rìndé …

Foto kan ti Komisanna fun Eto Iroyin ati Ipile Ise, Ogbeni Steve Ayorinde, gbe jade lojo Satide ti se ofofo bi akorin naa se se ojo ibi re.
Ninu foto naa, a ri Wasiu to n se Ayorinde ati alejo miiran lalejo.
Funra re lo n ba won fi obe ge awon midin-miidin ti won n je.
Ayorinde naa wa gbe foto naa sori ero alatagba Facebook, nibi to ti so pe, ‘Bobo no go die unless to ba d’arugbo’.
Eyi ko yani lenu nitori pe ore ni Ayorinde pelu Wasiu ko to di pe o bo sinu ijoba.
Koda, opo igba ni won maa n pade ni ilu oyinbo tele.
Nigba ti awon eniyan ri foto naa, ti won ri bi Wasiu tun se ri bii omo ogbon odun ninu kootu oyinbo alailapa to wo, won tun n fi igbesi aye re toro ni.
Won wa n so fun Ayorinde ko baa won bi Wasiu pe kin ni asiri ewa re, atipe ibo lo ti ri ajidewe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…