Èwo ló dùn jù nínú orin Wasiu?
Ni odun 1979 ni Ayinde Marshall koko se awon orin jade, eyi ti akole re je ABODE MECCA.
Sugbon odun 1084 ni irawo re bere sii yo, nigba to se awo Tala 84.
Lati igba naa ni Wasiu ti n da bi edun to tun n ro bi owe.
O ti se opo awo orin, ti awon kan si rinle gidi.
Lati da si ayeye K1 de Ultimate yii, IROYIN OWURO n beere lowo w ape ‘Ewo ni e gbe pe o dun julo ninu awon awo tabi orin Wasiu Ayinde?’
A ku ajoyo, tiwa naa a de o.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…