Bàbá Ẹniọlá Badmus náà di olóògbé
Alariya meji pataki padanu eni meji pataki to sun mo okan won timotimo laipe yii.
Awon amuludan naa ni akorin emi, Tope Alabi,; ati osere fiimu Eniola Badmus.
Iya Tope Alabi lo di oloogbe, ti iya naa n je, iyaafin Agnes Kehinde Obayomi.
Baba Eniola, Alagba Adesina Badmus naa je Olorun nipe, ni eni odun merindin-laadorun, 86 years.
Opo awon ololufe won lo n ba won kedun latigba naa, ti won si n sadura pe ki Olorun te awon oku si afefe rere.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…