Home ỌRỌ̀-AJÉ Akérédolú fa ìbínú yọ sí àwọn tó gé igi gẹdú

Akérédolú fa ìbínú yọ sí àwọn tó gé igi gẹdú

Gege bi Gomina Ipinle Ondo, Alagba Rotimi Akeredolu, ti n mura lati yan awon eniyan to yoo ba a sise, o ti bere sii gbe awon igbese ti yoo mu ayipada ba ipinle naa o.
O ti fi ofin de igi gedu gige, to si so pe eni ti owo ba ba to n ge igi ni igekugee, ijoba yoo fimu re fon fere.
O ni ofin naa gbodo mmule ni gbogbo ijoba ibile mejidinlogun to wa ni ipinle naa.
Bakan naa, Gomina ni gbogbo oun ti yoo mu ki oro aje o pada bo sipo ni oun yoo se.
O ni iroyin ti kan oun pe awon obayeje kan n se modaru lori igi gedu gige.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…