Home iroyin Àjàgà tó wà lórùn àwọn ọ̀dọ́ l’Áfíríkà kìí jẹ̀ kí n rórun sùn – TB Joshua
iroyin - òpómúléró - Orisirisi - March 5, 2017

Àjàgà tó wà lórùn àwọn ọ̀dọ́ l’Áfíríkà kìí jẹ̀ kí n rórun sùn – TB Joshua

Oludasile ijo Synagogue of All Nations, Pastor TB Joshua, ti so pe oun ti setan lati siwaju ni nu awon eto ti yoo mu iroun baa won odo langba kaakiri Aaffirika.
TB Joshua woye pe ajaga to wa lorun awon odo tip o ju, ti airise, iya ati ise si mu won lorun.
O ni kinni naa wa lokun oun debi wi pe ti oun ba ti ranti iya to n je awon odo langba, kii je ki oun ri oorun sun.
Ojise Olorun naa wa so pe oun yoo se gbogbo oun to wa ni ikapa oun lati mu kuro ninu ajaga naa.
Ipinnu pasito naa ti fa ki awon eniyan kan maa yombo re.
Lara won ni olori odo fun egbe APC, Ogbeni Timi Frank, to so pe igbese pataki ni TB Joshua fe gbe.
Tope Alabi sedaro iya re to ku,

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…