Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Ọ̀nà ọ̀fun ọ̀nà ọ̀run – Ideye fẹ́ lọ bá Mikel ní China, owó tabua ni wọ́n fẹ́ gbé fún un
ERÉ ÌDÁRAYÁ - February 26, 2017

Ọ̀nà ọ̀fun ọ̀nà ọ̀run – Ideye fẹ́ lọ bá Mikel ní China, owó tabua ni wọ́n fẹ́ gbé fún un

Ibinu owo ni egbe agbaboolu Tianjin Teda fi n fa agbaboolu Naijiria, Brown Ideye, eni ti won fe ko darapo mo akegbe re, Mikel Obi, ni orile ede China.

Igba ti nnkan ko rogbo fun Mikel mo ni o gba kadara, to kuro ni agbo EPL ni London, nibi to ti wa pelu Chelsea tele.

Owo nla ni oun naa n gba losoose.

Ni bayii, egbe agbaboolu Teda ti fi opo milionu dola lo Ideye naa, leyii ti a gbo pe oun naa ti fe pa okan re po lati lo je mula naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…